ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Jèhófà Máa Ń San Àwọn Tó Bá Nígboyà Lẹ́san

Yorùbá
Jèhófà Máa Ń San Àwọn Tó Bá Nígboyà Lẹ́san
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202023168/univ/art/202023168_univ_sqr_xl.jpg
mwb23 May ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Máa Ń San Àwọn Tó Bá Nígboyà Lẹ́san

Jèhófà Máa Ń San Àwọn Tó Bá Nígboyà Lẹ́san

Jèhóṣábéátì àti ọkọ ẹ̀ Jèhóádà gbé Jèhóáṣì pa mọ́ kí Ataláyà má baà pa á (2Kr 22:11, 12; w09 4/1 24 ¶1-2)

Jèhóádà gbé ìgbésẹ̀ akin, ó sì sọ Jèhóáṣì di ọba (2Kr 23:1-11, 14, 15; w09 4/1 24 ¶3-5)

Nítorí pé Jèhóádà nígboyà, ó sì ṣe ohun tó tọ́, wọ́n sin ín síbi tí wọ́n ń sin àwọn ọba sí (2Kr 24:15, 16; it-1 379 ¶5)

RONÚ LÓRÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ: Àwọn apá wo nínú ìjọsìn mi ni mo ti lè fi hàn pé mo nígboyà?