Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ June 26–July 2, 2023
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202023182/univ/art/202023182_univ_sqr_xl.jpg
mwb23 May ojú ìwé 14

June 26–July 2

Ẹ́SÍRÀ 1-3

June 26–July 2
  • Orin 75 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Yọ̀ǹda Ara Ẹ fún Iṣẹ́ Jèhófà”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Ẹsr 1:5, 6​—Kí la rí kọ́ nínú ohun táwọn ọmọ Ísírẹ́lì tí ò kúrò ní Bábílónì ṣe fún àwọn tó lọ tún tẹ́ńpìlì kọ́ ní Jerúsálẹ́mù? (w06 1/15 19 ¶1)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ẹsr 2:58-70 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI