ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ìgbéraga Mú Kí Ábúsálómù Ṣọ̀tẹ̀

Yorùbá
Ìgbéraga Mú Kí Ábúsálómù Ṣọ̀tẹ̀
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022184/univ/art/202022184_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 May ojú ìwé 14

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ìgbéraga Mú Kí Ábúsálómù Ṣọ̀tẹ̀

Ìgbéraga Mú Kí Ábúsálómù Ṣọ̀tẹ̀

Ábúsálómù wá ògo fún ara ẹ̀ (2Sa 15:1; it-1 860)

Ábúsálómù dọ́gbọ́n fa ojú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì mọ́ra (2Sa 15:2-6; w12 7/15 13 ¶5)

Ábúsálómù gbìyànjú láti gbàjọba lọ́wọ́ bàbá rẹ̀ (2Sa 15:10-12; it-1 1083-1084)

A gbọ́dọ̀ ṣọ́ra fún wíwá ipò ọlá lójú méjèèjì. Torí náà, ó yẹ ká máa yẹ ọkàn wa wò látìgbàdégbà. Dípò ká máa wá bá a ṣe máa gbayì lójú àwọn míì, ire wọn ló yẹ kó jẹ wá lọ́kàn.​—Flp 2:3, 4