ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti Ọ̀sẹ̀ June 13-19, 2022

Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti Ọ̀sẹ̀ June 13-19, 2022
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022177/univ/art/202022177_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 May ojú ìwé 10
June 13-19
  • Orin 121 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Má Ṣe Gba Èròkerò Láyè”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 2Sa 12:13​—Kí nìdí tí Jèhófà ò fi jẹ́ kí wọ́n pa Dáfídì àti Bátí-ṣébà nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn? (it-1 590 ¶1)

    • Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Sa 11:1-15 (th ẹ̀kọ́ 10)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI