MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ TẸ̀ Ẹ̣́ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Nígbà Àkọ́kọ́ Ìbéèrè: Kí ni Ọlọ́run fẹ́ fún àwa èèyàn? Bíbélì: Jẹ 1:28 Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run máa ṣe ohun tó ní lọ́kàn fún wa? WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́: bhs 29 ¶1 Ìpadàbẹ̀wò Ìbéèrè: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run máa ṣe ohun tó ní lọ́kàn fún wa? Bíbélì: Ais 55:11 Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni ayé ṣe máa rí nígbà tí Ọlọ́run bá ṣe ohun tó ní lọ́kàn? WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́: bhs 29 ¶2 Pa Dà Èyí Tó Kàn