Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti Ọ̀sẹ̀ May 31–June 6, 2021
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202021171/univ/art/202021171_univ_sqr_xl.jpg
mwb21 May ojú ìwé 8

May 31–June 6

DIUTARÓNÓMÌ 1-2

May 31–June 6
  • Orin 125 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ọlọ́run Ló Ni Ìdájọ́”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Di 1:19; 2:7​—Báwo ni Jèhófà ṣe bójú tó àwọn èèyàn rẹ̀ nígbà tí wọ́n rìnrìn àjò fún ogójì ọdún nínú ‘aginjù tó tóbi, tó sì ń bani lẹ́rù’? (w13 9/15 9 ¶9)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 1:1-18 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI