ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

“O Ò Gbọ́dọ̀ Bá Wọn Dána Rárá”

Yorùbá
“O Ò Gbọ́dọ̀ Bá Wọn Dána Rárá”
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202021181/univ/art/202021181_univ_sqr_xl.jpg
mwb21 May ojú ìwé 14

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“O Ò Gbọ́dọ̀ Bá Wọn Dána Rárá”

“O Ò Gbọ́dọ̀ Bá Wọn Dána Rárá”

Jèhófà sọ fáwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé wọn ò gbọ́dọ̀ fẹ́ ẹni tí ò sin òun (Di 7:3; w12 7/1 29 ¶2)

Jèhófà ò fẹ́ káwọn ìránṣẹ́ òun jìyà, kò sì fẹ́ kí wọ́n ní ẹ̀dùn ọkàn (Di 7:4; w15 3/15 30-31)

Ohun tí Jèhófà fẹ́ ká ṣe lórí ọ̀rọ̀ ìgbéyàwó kò tíì yí pa dà (1Kọ 7:39; 2Kọ 6:14; w15 8/15 26 ¶12)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àǹfààní wo ni màá rí tí mo bá fẹ́ “kìkì nínú Olúwa”?’