ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà
Àwọn òbí gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà (Di 6:5; w05 6/15 20 ¶11)
Wọ́n gbọ́dọ̀ fi àpẹẹrẹ tó dáa lélẹ̀ fáwọn ọmọ wọn (Di 6:6; w07 5/15 15-16)
Wọ́n gbọ́dọ̀ máa kọ́ àwọn ọmọ nípa Jèhófà léraléra (Di 6:7; w05 6/15 21 ¶14)
Yàtọ̀ sígbà tẹ́ ẹ bá ń ṣe ìjọsìn ìdílé, àwọn ìgbà wo lo tún lè kọ́ àwọn ọmọ rẹ kí wọ́n lè nífẹ̀ẹ́ Jèhófà àtàwọn ìlànà rẹ̀?

