Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ May 25-31, 2020
/assets/ct/08c9985de2/images/syn_placeholder_sqr.png
mwb20 May ojú ìwé 6
May 25-31
  • Orin 120 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì​—Fídíò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà bi wọ́n pé: Báwo ni arákùnrin yìí ṣe nasẹ̀ Ìwé Mímọ́ lọ́nà tó yẹ? Kí nìdí tí arákùnrin náà fi lo ìwé Bíbélì Kọ́ Wa? Báwo ló sì ṣe nasẹ̀ rẹ̀?

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 15)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 34 ¶18 (th ẹ̀kọ́ 8)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI