Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ May 18-24, 2020
/assets/ct/fa815d8e9f/images/syn_placeholder_sqr.png
mwb20 May ojú ìwé 5
May 18-24
  • Orin 8 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́​—Fídíò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Kí ló jẹ́ ká rí i pé ọkọ àtìyàwó yìí jọ múra ìpadàbẹ̀wò náà sílẹ̀? Kí ni arákùnrin yìí ṣe kí onílé lè rí ìdí tó fi ká Ìwé Mímọ́?

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 11)

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún un ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 13)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 128

  • Máa Fara Dà Á Tí Wọ́n Bá Hùwà Àìdáa Sí Ẹ Bíi Ti Jósẹ́fù: (6 min.) Ẹ kọ́kọ́ wo fídíò Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Máa Fara Dà Á Tí Wọ́n Bá Rẹ́ Ẹ Jẹ. Lẹ́yìn náà, pe àwọn ọmọdé mélòó kan wá sórí pèpéle, kó o sì bi wọ́n pé: Báwo ni wọ́n ṣe hùwà àìdáa sí Kọ́lá àti Tósìn? Ẹ̀kọ́ wo lo rò pé wọ́n kọ́ nínú ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Jósẹ́fù?

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (9 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 19 ¶8-14

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 124 àti Àdúrà