Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ May 11-17, 2020
/assets/ct/79e1b14fff/images/syn_placeholder_sqr.png
mwb20 May ojú ìwé 4
May 11-17
  • Orin 33 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jèhófà Ò Pa Jósẹ́fù Tì”: (10 min.)

    • Jẹ 39:1​—Jósẹ́fù di ẹrú ní Íjíbítì (w14 11/⁠1 12 ¶4-5)

    • Jẹ 39:​12-14, 20​—Wọ́n parọ́ mọ́ Jósẹ́fù, wọ́n sì fi í sẹ́wọ̀n (w14 11/1 14-15)

    • Jẹ 39:​21-23​—Jèhófà ò fi Jósẹ́fù sílẹ̀ nígbà kankan (w14 11/1 15 ¶2)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Jẹ 38:​9, 10​—Kí nìdí tí Jèhófà fi pa Ónánì? (it-2 555)

    • Jẹ 38:​15-18​—Kí la lè sọ nípa ohun tí Júdà àti Támárì ṣe? (w04 1/15 30 ¶4-5)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 38:​1-19 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́​—Fídíò: (4 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Báwo ni arábìnrin yìí ṣe jẹ́ kí onílé lóye ohun tó ń sọ? (th ẹ̀kọ́ 17) Ọ̀nà wo lo rò pé akéde yìí lè gbà fi ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ lọ onílé?

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 1)

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 11)

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà fún onílé ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 6)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI