Jósẹ́fù gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà nígbà tó wà lẹ́wọ̀n ní Íjíbítì

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI May 2020

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ìjíròrò tó dá lórí ikú àti àjíǹde.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Àwọn Ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù Hùwà Ìkà Sí I Torí Wọ́n Ń Jowú Rẹ̀

Báwo ni ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Jósẹ́fù ṣe jẹ́ ká rí àkóbá tí owú máa ń fà?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ṣé O Ti Múra Sílẹ̀?

Àjálù lè ṣẹlẹ̀ níbikíbi àti nígbàkigbà. Báwo la ṣe lè múra sílẹ̀?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Ò Pa Jósẹ́fù Tì

Jèhófà ò pa Jósẹ́fù tì nígbà tó dojú kọ ìṣòro. Kí la rí kọ́ nínú èyí?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Sá fún Ìṣekúṣe Bíi Ti Jósẹ́fù

Báwo la ṣe lè fìwà jọ Jósẹ́fù ká sì sá fún ìṣekúṣe?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Gba Jósẹ́fù Sílẹ̀

Báwo ni Jósẹ́fù ṣe ṣe gbogbo ohun tó lè ṣe nínú ipò tó wà, báwo sì ni Jèhófà ṣe gbà á sílẹ̀?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jósẹ́fù Kó Ara Ẹ̀ Níjàánu Lọ́nà Tó Lágbára

Látìgbà táwọn ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù ti tà á sóko ẹrú, Jósẹ́fù tún rí àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ fúngbà àkọ́kọ́ láìròtẹ́lẹ̀. Ẹ̀kọ́ wo la rí kọ́ nípa bí Jósẹ́fù ṣe hùwà pa dà?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Máa Fọkàn Yàwòrán Ohun Tó Ò Ń Kà

Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo la lè rí tá a bá ronú jinlẹ̀ lórí ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Jósẹ́fù àti ìdílé rẹ̀?