Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | GÁLÁTÍÀ 1-3

“Mo Ta Kò Ó Lójúkojú”

“Mo Ta Kò Ó Lójúkojú”

2:11-14

Báwo ni ìtàn yìí ṣe kọ́ wa láwọn ẹ̀kọ́ tó wà nísàlẹ̀ yìí?

  • A gbọ́dọ̀ jẹ́ onígboyà.​—w18.03 31-32 ¶16

  • Ìbẹ̀rù èèyàn jẹ́ ìdẹkùn.​—it-2 587 ¶3

  • Àwọn èèyàn Jèhófà kì í ṣe ẹni pípé, títí kan àwọn tó ń mú ipò iwájú.​—w10 6/15 17-18 ¶12

  • A gbọ́dọ̀ máa gbìyànjú ní gbogbo ìgbà ká lè fa ẹ̀mí kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà tu kúrò ní ọkàn wa.​—w18.08 9 ¶5