Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

May 13-​19

2 KỌ́RÍŃTÌ 7-10

May 13-​19
 • Orin 109 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìrànwọ́ Tá À Ń Ṣe”: (10 min.)

  • 2Kọ 8:1-3​—Àwọn ará tó wà ní Makedóníà ṣe “kọjá agbára wọn,” láti ran àwọn ará tó wà ní Jùdíà lọ́wọ́ (w98 11/1 25 ¶1; kr 209 ¶1)

  • 2Kọ 8:4​—Tá a bá ń ṣèrànwọ́ fún àwọn ará wa tó nílò ìrànlọ́wọ́, ara “iṣẹ́ òjíṣẹ́” wa là ń ṣe (kr 209-210 ¶4-6)

  • 2Kọ 9:7​—“Ọlọ́run nífẹ̀ẹ́ ẹni tó ń fúnni pẹ̀lú ìdùnnú” (kr 196 ¶10)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • 2Kọ 9:15​—Kí ni “ẹ̀bùn ọ̀fẹ́” Ọlọ́run “tí kò ṣeé ṣàpèjúwe”? (w16.01 9 ¶2)

  • 2Kọ 10:17​—Kí ló túmọ̀ sí láti “máa fi Jèhófà yangàn”? (g99 7/8 18-19)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 2Kọ 7:1-12 (th ẹ̀kọ́ 12)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 1)

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 2)

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 4)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI