Ètò ìrànwọ́ fáwọn tí àjálù dé bá ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI May 2019

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ìjíròrò tó dá lórí ikú àti àjíǹde.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“A Kò Juwọ́ Sílẹ̀”

Tá a bá ń gbájú mọ́ àwọn ìbùkún tá a máa gbádùn nínú Ìjọba Ọlọ́run lọ́jọ́ iwájú, ìyẹn máa ràn wá lọ́wọ́ láti ní ayọ̀, a ò sì ní juwọ́ sílẹ̀.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìrànwọ́ Tá À Ń Ṣe

Tá a bá ń ṣèrànwọ́ fún àwọn ará wa tó wà nínú ìṣòro, ara iṣẹ́ ìsìn ọlọ́wọ̀ là ń ṣe.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Bí Àwọn Ará Wa Ní Caribbean Ṣe Jàǹfààní Nínú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìrànwọ́ Tá À Ń Ṣe

Báwo ni àwọn ará ṣe ṣèrànwọ́ fún àwọn Kristẹni ẹlẹgbẹ́ wọn tó ń gbé ní Caribbean?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ẹ̀gún Nínú Ara Pọ́ọ̀lù

Kí ló ṣeé ṣe kí Pọ́ọ̀lù máa tọ́ka sí nígbà tó sọ pé òun ní “ẹ̀gún” nínú ara?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

O Lè Ṣàṣeyọrí Láìka Ti “Ẹ̀gún” Tó Wà Nínú Ara Rẹ Sí!

Báwo la ṣe lè gbára lé Jèhófà, kí la sì lè ṣe láti fara dà àwọn ìṣòro yìí?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Mo Ta Kò Ó Lójúkojú”

Aláìpé ni wá, torí náà, a gbọ́dọ̀ máa gbìyànjú ní gbogbo ìgbà ká lè fa ẹ̀mí kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà tu kúrò ní ọkàn wa.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Bí Gbogbo Wa Ṣe Lè Máa Bójú Tó Àwọn Ibi Ìjọsìn Wa

Àwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba wa kì í ṣe ilé kan lásán; ibi tá a yà sí mímọ́ fún Jèhófà ni wọ́n.