ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Jèhófà Ń Bù Kún Àwọn Onírẹ̀lẹ̀ Ó sì Ń Fìyà Jẹ Àwọn Agbéraga

Yorùbá
Jèhófà Ń Bù Kún Àwọn Onírẹ̀lẹ̀ Ó sì Ń Fìyà Jẹ Àwọn Agbéraga
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202017173/univ/art/202017173_univ_sqr_xl.jpg

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 49-50

Jèhófà Ń Bù Kún Àwọn Onírẹ̀lẹ̀ Ó sì Ń Fìyà Jẹ Àwọn Agbéraga

Jèhófà Ń Bù Kún Àwọn Onírẹ̀lẹ̀ Ó sì Ń Fìyà Jẹ Àwọn Agbéraga

50:4-7

  • Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó ronú pìwà dà máa fò fáyọ̀ nígbà tí Jèhófà bá mú wọn kúrò nígbèkùn

  • Wọ́n á tún mú ẹ̀jẹ́ wọn ṣẹ lákọ̀tun, wọ́n á sì rìnrìn àjò tó jìn pa dà sí Jerúsálẹ́mù kí wọ́n lè pa dà máa jọ́sìn Ọlọ́run tòótọ́

50:29, 39

  • Bábílónì kò ní lọ láìjìyà torí ìwà ìkà tó burú jáì tó hù sí àwọn èèyàn Jèhófà

  • Àsọtẹ́lẹ̀ Ọlọ́run ní ìmúṣẹ, Bábílónì di ahoro, kò sí ẹnì kankan tó ń gbé ibẹ̀ títí dòní