April 13-19
ÀÌSÁYÀ 52-53
Orin 18 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
Wọ́n ń mú Jésù lọ síbi tí wọ́n ti fẹ́ pa á
1. Ẹ Wo Bí Jésù Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Wa Tó!
(10 min.)
Wọ́n máa kórìíra Jésù (Ais 53:3; Mt 26:67, 68; w10 11/15 7 ¶2)
Jésù máa jẹ́ kí wọ́n fìyà jẹ òun (Ais 53:7; ip-2 205 ¶25)
Ìfẹ́ ló mú kí Jésù gbà láti jìyà kó lè ṣe ohun tí Jèhófà fẹ́, kó sì kó ẹ̀ṣẹ̀ wa lọ (Ais 53:10-12; Jo 14:31; 15:13)
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
-
Ais 52:11—Kí la rí kọ́ nínú àsọtẹ́lẹ̀ yìí? (it “Àwọn Ohun Èlò” ¶2)
-
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Ais 53:3-12 (th ẹ̀kọ́ 10)
4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa
(4 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (lmd ẹ̀kọ́ 4 kókó 4)
5. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa
(3 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Lo ọ̀kan nínú àwọn àkòrí tó wà ní àfikún A nínú ìwé Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Èèyàn láti bá ẹni náà sọ̀rọ̀. (lmd ẹ̀kọ́ 3 kókó 3)
6. Pa Dà Lọ
(5 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ ẹnì kan tó wá sí Ìrántí Ikú Kristi. (lmd ẹ̀kọ́ 8 kókó 3)
Orin 20
7. Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Ìfẹ́ Tó Ga Jù Lọ
(15 min.) Ìjíròrò.
Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà. Lẹ́yìn náà, béèrè pé:
-
Kí ló mú ká gbà pé ẹ̀bùn ni ìràpadà tí Jésù san?
-
Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọrírì ẹ̀?
8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) lfb ẹ̀kọ́ 76-77

