Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ April 10-16, 2023
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202023092/univ/art/202023092_univ_sqr_xl.jpg
mwb23 March ojú ìwé 10

April 10-16

2 KÍRÓNÍKÀ 8-9

April 10-16
  • Orin 88 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ọbabìnrin Ṣébà Mọyì Kéèyàn Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 2Kr 9:19​—Kí ló ṣeé ṣe kí àwọn ère kìnnìún méjìlá tó wà ní bi ìtẹ́ Sólómọ́nì ṣàpẹẹrẹ? (it-2 1097)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Kr 8:1-16 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI