ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Tó O Bá Ṣàṣeyọrí

Yorùbá
Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Tó O Bá Ṣàṣeyọrí
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022089/univ/art/202022089_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 March ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Tó O Bá Ṣàṣeyọrí

Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Tó O Bá Ṣàṣeyọrí

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yin Dáfídì (1Sa 18:5-7; w04 4/1 15 ¶4)

Jèhófà jẹ́ kí Dáfídì ṣàṣeyọrí nínú gbogbo ohun tó ṣe (1Sa 18:14)

Dáfídì lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀ láìka àṣeyọrí tó ṣe sí (1Sa 18:22, 23; w18.01 28 ¶6-7)

Kí nìdí tó fi yẹ ká lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀ tí Jèhófà bá mú ká ṣàṣeyọrí? Kí lá jẹ́ ká lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀?