ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti Ọ̀sẹ̀ March 21-27, 2022

Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti Ọ̀sẹ̀ March 21-27, 2022
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022085/univ/art/202022085_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 March ojú ìwé 4

March 21-27

1 SÁMÚẸ́LÌ 16-17

March 21-27
  • Orin 7 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ogun Náà Jẹ́ Ti Jèhófà”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 1Sa 16:14​—Kí ló túmọ̀ sí nígbà tí Bíbélì sọ pé ‘Jèhófà jẹ́ kí ẹ̀mí búburú’ máa da Sọ́ọ̀lù láàmú? (it-2 871-872)

    • Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Sa 16:1-13 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi: (2 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 11)

  • Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi: (3 min.) Pe ẹni tẹ́ ẹ jọ ń ṣiṣẹ́, ọmọ iléèwé rẹ tàbí mọ̀lẹ́bí rẹ tó o ti wàásù fún nígbà kan rí wá sí Ìrántí Ikú Kristi. (th ẹ̀kọ́ 2)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Pa dà lọ sọ́dọ̀ ẹnì kan tó nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, tó sì gba ìwé ìkésíni. (th ẹ̀kọ́ 4)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Pa dà lọ sọ́dọ̀ ẹnì kan tó nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, tó sì gba ìwé ìkésíni. Sọ fún ẹni náà pé kó lọ sórí ìkànnì wa. (th ẹ̀kọ́ 20)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI