ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Gidi

Yorùbá
Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Gidi
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022092/univ/art/202022092_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 March ojú ìwé 8

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Gidi

Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Gidi

Tí ọ̀rẹ́ rẹ bá ní ìdààmú ọkàn, tù ú nínú kó o sì gbà á níyànjú (1Sa 20:1, 2; w19.11 7 ¶18)

Kìlọ̀ fún ọ̀rẹ́ ẹ tó bá fẹ́ kó sínú ewu (1Sa 20:12, 13; w08 2/15 8 ¶7)

Gbèjà ọ̀rẹ́ ẹ táwọn èèyàn bá ń sọ̀rọ̀ ẹ̀ láìdáa (1Sa 20:30-32; w09 10/15 19 ¶11)

Ọ̀rẹ́ gidi pọ̀ nínú ètò Ọlọ́run. Àmọ́ kó o tó lè ní ọ̀rẹ́ gidi, ìwọ náà gbọ́dọ̀ jẹ́ ọ̀rẹ́ gidi. Ta ni wàá fẹ́ yàn lọ́rẹ̀ẹ́ nínú ìjọ yín?