ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ṣé O Máa Ń Hùwà Láìronú?

Yorùbá
Ṣé O Máa Ń Hùwà Láìronú?
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022099/univ/art/202022099_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 March ojú ìwé 14

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ṣé O Máa Ń Hùwà Láìronú?

Ṣé O Máa Ń Hùwà Láìronú?

Ohun tí Dáfídì béèrè lọ́wọ́ Nábálì ò pọ̀ jù, àmọ́ Nábálì sọ̀rọ̀ burúkú sí i (1Sa 25:7-11; ia 78-79 ¶10-12)

Dáfídì pinnu láti pa gbogbo àwọn ọkùnrin tó wà nílé Nábálì (1Sa 25:13, 21, 22)

Ábígẹ́lì kò jẹ́ kí Dáfídì jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ (1Sa 25:25, 26, 32, 33; ia 80 ¶18)

BI ARA RẸ PÉ: ‘Ṣé mo máa ń hùwà láìronú tí inú bá ń bí mi tàbí tí mo bá rẹ̀wẹ̀sì? Ṣé mo máa ń ra nǹkan tó bá ṣáà ti wù mí? Àbí mo máa ń simẹ̀dọ̀, kí n sì fara balẹ̀ ro ìgbẹ̀yìn ọ̀rọ̀ kí n tó gbé ìgbésẹ̀?’​—Owe 15:28; 22:3.