Fífi fídíò kọ́ ẹnì kan lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lórílẹ̀-èdè South Africa

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI March 2019

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ìjíròrò tó dá lórí ohun tí Ọlọ́run fẹ́ ṣe fún àwa èèyàn.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ohun Tó Túmọ̀ Sí Láti Fi Ìfẹ́ Hàn Síra Wa

Tẹ́nì kan bá ṣẹ̀ wá, tá a bá fẹ́ fi hàn pé a nífẹ̀ẹ́ ara wa, kí ló yẹ ká ṣe?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bẹ Jèhófà Pé Kó Fún Ẹ Ní Ìfaradà Kó sì Tù Ẹ́ Nínú

Jèhófà Ọlọ́run máa ń lo Bíbélì Ọ̀rọ̀ rẹ̀ láti tù wá nínú, ká sì ní ìfaradà.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ṣé Ẹni Tara Ni Ẹ́ Tàbí Ẹni Tẹ̀mí?

Gbogbo wa ló yẹ ká máa sapá láti di ẹni tẹ̀mí, ká sì máa túbọ̀ sún mọ́ Jèhófà.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I​—Bó O Ṣe Lè Kọ Lẹ́tà

Kí làwọn nǹkan tó yẹ kó o fi sọ́kàn tó o bá ń kọ lẹ́tà sí ẹni tó ò mọ̀ rí?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Àpẹẹrẹ Lẹ́tà Tá A Lè Fi Wàásù

Kọ lẹ́tà náà lọ́nà tó máa fi wà ní ìbámu pẹ̀lú àṣà àti bí wọ́n ṣe ń ṣe nǹkan ládùúgbò yín.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Ìwúkàrà Díẹ̀ Ní Í Mú Gbogbo Ìṣùpọ̀ Di Wíwú”

Báwo ni ìyọlẹ́gbẹ́ ṣe ń fi hàn pé a nífẹ̀ẹ́?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Máa Fi Fídíò Kọ́ Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

Ṣé o máa ń lo àwọn fídíò tó o bá ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?