ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Wọn Ò Ṣe Ohun Tí Jèhófà Fẹ́ Mọ́

Yorùbá
Wọn Ò Ṣe Ohun Tí Jèhófà Fẹ́ Mọ́
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202017086/univ/art/202017086_univ_sqr_xl.jpg

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 5-7

Wọn Ò Ṣe Ohun Tí Jèhófà Fẹ́ Mọ́

Wọn Ò Ṣe Ohun Tí Jèhófà Fẹ́ Mọ́

7:1-4, 8-10, 15

  • Jeremáyà fi ìgboyà tú àṣírí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti ìwà àgàbàgebè wọn

  • Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ka tẹ́ńpìlì sí oògùn ajẹ́bíidán tó máa dáàbò bò wọ́n

  • Jèhófà jẹ́ kí wọ́n mọ̀ pé àwọn ẹbọ tí wọ́n ń rú kò lè bo ìwà àìtọ́ wọn mọ́lẹ̀

Bi ara rẹ pé: Báwo ló ṣe lè dá mi lójú pé ìjọsìn mi bá ìfẹ́ inú Jèhófà mu àti pé kì í ṣe ìjọsìn ojú lásán?

Jeremáyà dúró lẹ́nu ọ̀nà ilé Jèhófà