ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ẹ̀rí ní June 2020

Yorùbá
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ẹ̀rí ní June 2020
/assets/ct/28ada02fb0/images/syn_placeholder_sqr.png
mwb20 June ojú ìwé 1

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́ *

Ìbéèrè: Ṣé ọjọ́ ìkẹyìn la wà yìí?

Bíbélì: 2Ti 3:1-5

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló máa ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn tí àwọn ọjọ́ ìkẹyìn yìí bá dópin?

○● ÌPADÀBẸ̀WÒ

Ìbéèrè: Kí ló máa ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn tí àwọn ọjọ́ ìkẹyìn yìí bá dópin?

Bíbélì: Ifi 21:​3, 4

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí la lè ṣe ká bàa lè gbádùn àwọn nǹkan tí Ọlọ́run ṣèlérí?

^ ìpínrọ̀ 2 Bẹ̀rẹ̀ láti oṣù yìí, nígbà àkọ́kọ́ àti ìpadàbẹ̀wò nìkan lá máa wà nínú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ.