Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ June 1-7, 2020
/assets/ct/29206d32a6/images/syn_placeholder_sqr.png
mwb20 June ojú ìwé 2
June 1-7
  • Orin 130 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Jósẹ́fù Dárí Ji Àwọn Ẹ̀gbọ́n Rẹ̀”: (10 min.)

    • Jẹ 44:1, 2​—Jósẹ́fù dán àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ wò (w15 5/1 14-15)

    • Jẹ 44:33, 34​—Júdà bẹ Jósẹ́fù pé kó dá Bẹ́ńjámínì sílẹ̀

    • Jẹ 45:4, 5​—Jósẹ́fù fara wé Jèhófà ní ti bó ṣe dárí ji àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Jẹ 44:13​—Kí ló túmọ̀ sí tẹ́nì kan bá fa aṣọ rẹ̀ ya? (it-2 813)

    • Jẹ 45:5-8​—Kí ló lè ràn wá lọ́wọ́ láti fara dà á tí wọ́n bá hùwà àìdáa sí wa? (w04 8/15 15 ¶15)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 45:​1-15 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 58

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.)

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (5 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù June.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 19 ¶20-23

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 19 àti Àdúrà