ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI June 2020
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ nípa ọjọ́ ìkẹyìn ètò àwọn nǹkan yìí.
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Jósẹ́fù Dárí Ji Àwọn Ẹ̀gbọ́n Rẹ̀
Ẹ̀kọ́ wo lo rí kọ́ látinú àpẹẹrẹ Jósẹ́fù nípa ìdí tó fi yẹ ká máa dárí jini?
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Jèhófà Pèsè Oúnjẹ Lásìkò Ìyàn
Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ìyàn tẹ̀mí ń han aráyé léèmọ̀, ibo lo ti lè rí ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ oúnjẹ tẹ̀mí?
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Àwọn Àgbàlagbà Ní Ohun Púpọ̀ Láti Kọ́ Wa
Báwo làwọn àgbàlagbà ṣe jẹ́ àpẹẹrẹ ìgbàgbọ́ fún wa?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ẹ̀kọ́ Wo Ló Lè Kọ́ Lára Àwọn Kristẹni Tó Nírìírí?
Báwo lo ṣe lè jàǹfààní látinú ìrírí àwọn ará tó ti pẹ́ nínú ètò Ọlọ́run?
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Èmi Yóò Di Ohun Tí Mo Bá Fẹ́”
Báwo ni ìtumọ̀ orúkọ Ọlọ́run ṣe lè ṣe ẹ́ láǹfààní?
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Màá Wà Pẹ̀lú Rẹ Bí O Ṣe Ń Sọ̀rọ̀”
Báwo ni àpẹẹrẹ Mósè ṣe lè ràn ẹ̀ lọ́wọ́ láti borí ìbẹ̀rù tó o bá fẹ́ wàásù?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Bá A Ṣe Lè Lo Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
Báwo ló ṣe yẹ ká lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ nígbà tá a bá ní iṣẹ́ ọmọ ilé ẹ̀kọ́ àti nígbà tá a bá wà lóde ẹ̀rí?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
O Lè Wàásù Kó O sì Máa Kọ́ni!
Kí lá jẹ́ kó o nígboyà láti wàásù kó o sì máa kọ́ni?