ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ẹ̀rí ní June 2019

Yorùbá
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ẹ̀rí ní June 2019
/assets/ct/2fee4a8a5e/images/syn_placeholder_sqr.png

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Ṣé ọjọ́ ìkẹyìn la wà yìí?

Bíbélì: 2Ti 3:1-5

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló máa wá ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn tí àwọn ọjọ́ ìkẹyìn yìí bá dópin?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Kí ló máa wá ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn tí àwọn ọjọ́ ìkẹyìn yìí bá dópin?

Bíbélì: Ifi 21:3, 4

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí la lè ṣe ká bàa lè gbádùn àwọn nǹkan tí Ọlọ́run ṣèlérí?

○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Kí la lè ṣe ká bàa lè gbádùn àwọn nǹkan tí Ọlọ́run ṣèlérí?

Bíbélì: Jo 3:16

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló túmọ̀ sí láti ní ìgbàgbọ́?