Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ June 4-​10, 2018
/assets/ct/79e1b14fff/images/syn_placeholder_sqr.png

June 4-​10

MÁÀKÙ 15-16

June 4-​10
  • Orin 95 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Àsọtẹ́lẹ̀ Ṣẹ sí Jésù Lára”: (10 min.)

    • Mk 15:​3-5​—Ó dákẹ́ nígbà tí wọ́n fi ẹ̀sùn kàn án

    • Mk 15:​24, 29, 30​—Wọ́n ṣẹ́ kèké lórí aṣọ rẹ̀, wọ́n sì fi í ṣe yẹ̀yẹ́ (“pín ẹ̀wù àwọ̀lékè rẹ̀”, àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mk 15:24 nwtsty, “wọ́n á mi orí wọn síwá sẹ́yìn” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mk 15:29, nwtsty)

    • Mk 15:​43, 46​—Wọ́n sin òkú rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́rọ̀ (“Jósẹ́fù” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mk 15:43 nwtsty)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Mk 15:25​—Kí ló ṣeé ṣe kó jẹ́ ìdí tí ìyàtọ̀ fi wà nínú ìgbà tí wọ́n kan Jésù mọ́gi? (“wákàtí kẹta”, àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mk 15:25, nwtsty)

    • Mk 16:8​—Kí nìdí tí Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun lédè Gẹ̀ẹ́sì, tá a tún ṣe lọ́dún 2013 kò fi ní ìparí gígùn tàbí ìparí kúkúrú nínú ìwé Ìhìn Rere Máàkù? (“nítorí wọ́n ń bẹ̀rù” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mk 6:8, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mk 15:​1-15

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI