Yorùbá
Téèyàn Bá Ṣàìgbọràn, Ó Máa Jìyà Ẹ̀
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202023248/univ/art/202023248_univ_sqr_xl.jpg
mwb23 July ojú ìwé 5

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Téèyàn Bá Ṣàìgbọràn, Ó Máa Jìyà Ẹ̀

Téèyàn Bá Ṣàìgbọràn, Ó Máa Jìyà Ẹ̀

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kan fẹ́ àwọn obìnrin tó jẹ́ abọ̀rìṣà (Ẹsr 9:1, 2; w06 1/15 20 ¶1)

Wọn ò ṣègbọràn sí òfin tí Jèhófà fún wọn (Ẹsr 9:10-12)

Àwọn àti ìdílé wọn jìyà gan-an nítorí àìgbọràn wọn (Ẹsr 10:10, 11, 44)

Ire wa ni gbogbo àṣẹ Jèhófà wà fún. (w09 10/1 10 ¶6) Tá a bá jẹ́ onígbọràn, a ò ní jìyà bíi táwọn aláìgbọràn, a sì máa gbádùn ìbùkún Jèhófà títí láé.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àwọn ìṣòro wo ni mi ò bá ti kó sí ká sọ pé mi ò ṣègbọràn sí Jèhófà?’