Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ July 17-23, 2023
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202023247/univ/art/202023247_univ_sqr_xl.jpg
mwb23 July ojú ìwé 5

July 17-23

Ẹ́SÍRÀ 9-10

July 17-23
  • Orin 89 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Téèyàn Bá Ṣàìgbọràn, Ó Máa Jìyà Ẹ̀”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Ẹsr 10:44​—Kí nìdí tí wọ́n fi lé àwọn ìyàwó tó jẹ́ àjèjì náà lọ tọmọtọmọ? (w06 1/15 20 ¶2)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ẹsr 9:1-9 (th ẹ̀kọ́ 2)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI