Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ July 10-16, 2023
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202023245/univ/art/202023245_univ_sqr_xl.jpg
mwb23 July ojú ìwé 4

July 10-16

Ẹ́SÍRÀ 7-8

July 10-16
  • Orin 82 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ẹ́sírà Fi Ìwà Rẹ̀ Gbé Orúkọ Jèhófà Ga”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Ẹsr 8:1​—Kí nìdí tí ọ̀pọ̀ àwọn Júù tó wà ní Bábílónì ò fi fẹ́ bá Ẹ́sírà lọ sí Jerúsálẹ́mù? (w06 1/15 19 ¶10)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ẹsr 8:21-36 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI