Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ August 28–September 3, 2023
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202023262/univ/art/202023262_univ_sqr_xl.jpg
mwb23 July ojú ìwé 14

August 28–September 3

NEHEMÁYÀ 12-13

August 28–September 3
  • Orin 34 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà Tó O Bá Fẹ́ Yan Ọ̀rẹ́”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Ne 13:10​—Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ọmọ Léfì láwọn akọrin inú tẹ́ńpìlì, kí nìdí tí ẹsẹ Bíbélì yìí tún fi dárúkọ wọn lọ́tọ̀? (it-2 452 ¶9)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ne 12:27-39 (th ẹ̀kọ́ 2)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI