Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ August 21-27, 2023
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202023259/univ/art/202023259_univ_sqr_xl.jpg
mwb23 July ojú ìwé 12

August 21-27

NEHEMÁYÀ 10-11

August 21-27
  • Orin 37 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Wọ́n Yááfì Ohun Ìní Wọn fún Jèhófà”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Ne 10:34​—Kí nìdí tí wọ́n fi sọ pé káwọn èèyàn náà máa mú igi wá? (w06 2/1 11 ¶1)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ne 10:28-39 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI