ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ July 25-31, 2022

Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ July 25-31, 2022
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022250/univ/art/202022250_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 July ojú ìwé 7
July 25-31
  • Orin 76 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 17

  • Ẹ Jẹ́ Ká Máa Fi Tinútinú Ṣe Ìrúbọ (Sm 54:6): (9 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà.

  • Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Máa Lo Ara Ẹ Fáwọn Míì: (6 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, tó bá ṣeé ṣe, pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan, kó o sì bi wọ́n láwọn ìbéèrè yìí: Ibo ni Kọ́lá àti Tósìn fẹ́ lọ tẹ́lẹ̀ àmọ́ tí wọn ò lọ mọ́ torí bàbá àgbàlagbà yẹn? Báwo ni àpẹẹrẹ Jésù ṣe ran Kọ́lá lọ́wọ́? Àwọn nǹkan wo ni ìwọ náà ti ṣe fún Jèhófà àtàwọn míì?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 13 àti àlàyé ìparí ìwé 1

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 32 àti Àdúrà