Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ August 8-14, 2022
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022256/univ/art/202022256_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 July ojú ìwé 10

August 8-14

1 ÀWỌN ỌBA 3-4

August 8-14
  • Orin 88 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Bí Ọgbọ́n Ṣe Ṣeyebíye Tó”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 1Ọb 4:20—Kí ló gbàfiyèsí nínú gbólóhùn náà wọ́n “pọ̀ bí iyanrìn etí òkun”? (w98 2/1 11 ¶15)

    • Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Ọb 3:1-14 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI