ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Sólómọ́nì Fi Ìrẹ̀lẹ̀ Gbàdúrà Látọkàn Wá

Yorùbá
Sólómọ́nì Fi Ìrẹ̀lẹ̀ Gbàdúrà Látọkàn Wá
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022264/univ/art/202022264_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 July ojú ìwé 14

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Sólómọ́nì Fi Ìrẹ̀lẹ̀ Gbàdúrà Látọkàn Wá

Sólómọ́nì Fi Ìrẹ̀lẹ̀ Gbàdúrà Látọkàn Wá

Nígbà ayẹyẹ tí wọ́n fi ṣí tẹ́ńpìlì, Sólómọ́nì gbàdúrà àtọkànwá níwájú àwọn èèyàn náà (1Ọb 8:22; w09 11/15 9 ¶9-10)

Sólómọ́nì ò pàfiyèsí sí ara ẹ̀, kàkà bẹ́ẹ̀ Jèhófà ló fìyìn fún (1Ọb 8:23, 24)

Sólómọ́nì fi ìrẹ̀lẹ̀ gbàdúrà (1Ọb 8:27; w99 1/15 17 ¶7-8)

Àpẹẹrẹ tó dáa ni Sólómọ́nì fi lélẹ̀ fún gbogbo wa, pàápàá àwọn tó ń ṣojú àwùjọ nínú àdúrà. Kì í ṣe bí ọ̀rọ̀ wa ṣe dùn létí àwọn èèyàn ló yẹ kó jẹ wá lógún bí kò ṣe bí ohun tá a sọ ṣe rí lára Jèhófà.