Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ August 22-28, 2022
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022260/univ/art/202022260_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 July ojú ìwé 12

August 22-28

1 ÀWỌN ỌBA 7

August 22-28
  • Orin 7 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Lára Òpó Méjì”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 1Ọb 7:23​—Kí la rí kọ́ lára ‘Òkun tí wọ́n fi irin ṣe’ tó wà nínú tẹ́ńpìlì? (it-1 263)

    • Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Ọb 7:1-12 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI