Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ August 15-21, 2022
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022258/univ/art/202022258_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 July ojú ìwé 11

August 15-21

1 ÀWỌN ỌBA 5-6

August 15-21
  • Orin 122 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Fi ẹ̀yìn ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!​—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò. Sọ fún ẹni náà pé wàá pa dà wá dáhùn ìbéèrè tó wà ní àkòrí ẹ̀kọ́ 01. (th ẹ̀kọ́ 11)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Pa dà lọ sọ́dọ̀ ẹnì kan tó gba ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!​—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, kó o sì fi bá a ṣe ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì hàn án. (th ẹ̀kọ́ 2)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 06 kókó 5 (th ẹ̀kọ́ 9)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 91

  • A Rọ́wọ́ Jèhófà Lára Wa Nígbà Tá À Ń Kọ́ Àwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba: (15 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará pé: Àwọn nǹkan wo ló ṣẹlẹ̀ tó fi hàn pé Jèhófà bù kún iṣẹ́ kíkọ́ Gbọ̀ngàn Ìjọba ní Micronesia? Báwo ni ẹ̀mí mímọ́ ṣe ran àwọn ará tó ń kọ́ àwọn ilé ètò Ọlọ́run lọ́wọ́? Àwọn nǹkan wo ló mú kó o gbà pé Jèhófà bù kún iṣẹ́ ìkọ́lé ètò Ọlọ́run tó o ti lọ́wọ́ sí?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 16

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 20 àti Àdúrà