ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Sapá Kó O Lè Lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere

Yorùbá
Sapá Kó O Lè Lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022254/univ/art/202022254_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 July ojú ìwé 9

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI | OHUN TÓ O LÈ FI ṢE ÀFOJÚSÙN NÍ ỌDÚN IṢẸ́ ÌSÌN TÓ Ń BỌ̀

Sapá Kó O Lè Lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere

Sapá Kó O Lè Lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere

Kò dìgbà tí gbogbo nǹkan bá ń lọ geerege nígbèésí ayé rẹ kó o tó lè fi Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere (SKE) ṣe àfojúsùn rẹ. Ohun tó ṣe pàtàkì jù ni pé kó o ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú Jèhófà, kó o sì múra tán láti lọ sìn níbikíbi tí ètò Ọlọ́run bá rán ẹ lọ.​—Ais 6:8.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ JẸ́ KÍ ÌGBÀGBỌ́ MÚ KÓ O ṢE PÚPỌ̀ SÍ I​—SAPÁ KÓ O LÈ LỌ SÍ ILÉ Ẹ̀KỌ́ ÀWỌN AJÍHÌNRERE, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Kí ló mú kí Gabriel máa ṣiyèméjì lórí bóyá kóun lọ sílé ẹ̀kọ́ náà tàbí kóun má lọ, báwo sì ni Fílípì 4:13 ṣe ràn án lọ́wọ́?