ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ẹ̀rí ní July-August 2021

Yorùbá
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ẹ̀rí ní July-August 2021
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202021265/univ/art/202021265_univ_sqr_xl.jpg
mwb21 July ojú ìwé 16

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Nígbà Àkọ́kọ́

Ìbéèrè: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run kọ́ ló ń fìyà jẹ wá?

Bíbélì: Jem 1:13

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí nìdí tá a fi ń jìyà?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

Ìpadàbẹ̀wò

Ìbéèrè: Kí nìdí tá a fi ń jìyà?

Bíbélì: 1Jo 5:19

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ló ṣe máa ń rí lára Ọlọ́run tá a bá ń jìyà?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́: