ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Béèyàn Ṣe Lè Dájọ́ Lọ́nà Tó Tọ́

Yorùbá
Béèyàn Ṣe Lè Dájọ́ Lọ́nà Tó Tọ́
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202021248/univ/art/202021248_univ_sqr_xl.jpg
mwb21 July ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Béèyàn Ṣe Lè Dájọ́ Lọ́nà Tó Tọ́

Béèyàn Ṣe Lè Dájọ́ Lọ́nà Tó Tọ́

Yẹra fún ojúsàájú (Di 16:18, 19; it-1 343 ¶5)

Wádìí ọ̀rọ̀ náà dáadáa (Di 17:4-6; it-2 511 ¶7)

Jẹ́ káwọn míì ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí ẹjọ́ náà bá díjú (Di 17:8, 9; it-2 685 ¶6)

Àwọn alàgbà gbọ́dọ̀ rí i pé àwọn fi ìlànà yìí sílò tí wọ́n bá ń bójú tó ẹjọ́ kan nínú ìjọ.