ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

“Ẹ Má Ṣàníyàn Láé”

Yorùbá
“Ẹ Má Ṣàníyàn Láé”
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202021246/univ/art/202021246_univ_sqr_xl.jpg
mwb21 July ojú ìwé 5

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

“Ẹ Má Ṣàníyàn Láé”

“Ẹ Má Ṣàníyàn Láé”

Ní Ísírẹ́lì àtijọ́, Jèhófà máa ń ran àwọn aláìní lọ́wọ́. Àwọn ọ̀nà wo ni Jèhófà ń gbà ṣèrànwọ́ fáwọn ìránṣẹ́ ẹ̀ tó jẹ́ aláìní lónìí?

Kò yẹ ká máa ṣàníyàn, tó bá tiẹ̀ dà bíi pé ìṣòro wa pọ̀ lápọ̀jù. (Ais 30:15) Jèhófà máa pèsè gbogbo ohun tá a nílò tá a bá ṣáà ti fi Ìjọba ẹ̀ sípò àkọ́kọ́ láyé wa.​—Mt 6:31-33.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ MÁ ṢE JẸ́ KÍ ÌFẸ́ RẸ YẸ̀ LÁÉ . . . TÓ O BÁ TIẸ̀ JẸ́ TÁLÁKÀ​—CONGO, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Báwo làwọn ará tó ń gbé nítòsí ibi tí wọ́n ti fẹ́ ṣe àpéjọ ṣe ń fìfẹ́ hàn sáwọn tó máa ń rìnrìn àjò wá síbi àpéjọ náà?

  • Báwo ni fídíò yìí ṣe jẹ́ ká mọ̀ pé Jèhófà nífẹ̀ẹ́ àwọn aláìní?

  • Tá a bá tiẹ̀ jẹ́ tálákà, báwo la ṣe lè máa fìfẹ́ hàn sáwọn aláìní bíi ti Jèhófà?