ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti Ọ̀sẹ̀ August 16-22, 2021

Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti Ọ̀sẹ̀ August 16-22, 2021
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202021257/univ/art/202021257_univ_sqr_xl.jpg
mwb21 July ojú ìwé 12

August 16-22

DIUTARÓNÓMÌ 27-28

August 16-22
  • Orin 89 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Gbogbo Ìbùkún Yìí Máa . . . Bá Ọ”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Di 27:17​—Kí nìdí tí Jèhófà fi sọ pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò gbọ́dọ̀ sún ààlà ọmọnìkejì wọn? (it-1 360)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 28:1-14 (th ẹ̀kọ́ 11)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI