Àkànṣe àpéjọ nílùú Vienna, Austria

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI July 2018

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ìjíròrò tó dá lórí bí ìdílé ṣe lè láyọ̀.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ẹ Máa Díwọ̀n Fúnni Fàlàlà

Ẹni tó bá lawọ́ máa ń lo àkókò rẹ̀, okun rẹ̀ àti ohun ìní rẹ̀ láti ṣèrànwọ́ fáwọn èèyàn, kó sì fún wọn ní ìṣírí.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Kí Ló Túmọ̀ Sí Láti Di Ọmọlẹ́yìn?

Tó bá wá sí wa lọ́kàn pé ìgbà kan wà tí ‘nǹkan dáa fún wa jù báyìí lọ,’ kí ló yẹ ká ṣe?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Àpèjúwe Ará Samáríà

Àwọn ọmọlẹ́yìn gbọ́dọ̀ sa gbogbo ipá wọn láti fìfẹ́ hàn sí àwọn èèyàn, títí kan àwọn tó ṣeé ṣe kó yàtọ̀ sí wọn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Kí Nìdí Tó Fi Ṣe Pàtàkì Pé Ká Má Dá Sí Ọ̀ràn Òṣèlú? (Mik 4:2)

Tá a bá fẹ́ tẹ̀lé àpẹẹrẹ Ọlọ́run wa tí kì í ṣe ojúṣàájú, a gbọ́dọ̀ “máa ṣe ohun rere sí gbogbo ènìyàn.”

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Ẹ Níye Lórí Ju Ọ̀pọ̀ Ológoṣẹ́”

Tá a bá fẹ́ fìwà jọ Jèhófà, kí la lè ṣe fún àwọn tí wọ́n ń kojú inúnibíni?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Àpèjúwe Ọmọ Tó Sọ Nù

Àwọn ẹ̀kọ́ wo la rí kọ́ látinú àpèjúwe yìí nípa ọgbọ́n, ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀ àti béèyàn ṣe lè gbọ́kàn lé Jèhófà Ọlọ́run?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ọmọ Onínàákúnàá Pa Dà Wálé

Àwọn ẹ̀kọ́ pàtàkì wo la lè kọ́ nínú fídíò yìí?