ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti February 9-15, 2026

Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti February 9-15, 2026
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202026006/univ/art/202026006_univ_sqr_xl.jpg
mwb26 January ojú ìwé 11

February 9-15

ÀÌSÁYÀ 33-35

February 9-15

Orin 3 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. “Òun Ló Ń Mú Kí Nǹkan Lọ Bó Ṣe Yẹ Láwọn Àkókò Rẹ”

(10 min.)

Gbára lé Jèhófà nígbà ìṣòro, á sì fi ẹ́ lọ́kàn balẹ̀ (Ais 33:6a; w24.01 22 ¶7-8)

Bẹ Jèhófà pé kó fún ẹ lọ́gbọ́n àti ìmọ̀ kó o lè ṣe ìpinnu tó tọ́ (Ais 33:6b; w21.02 29 ¶10-11)

Gbára lé Jèhófà kó o sì rí bí Àìsáyà 33:24 ṣe máa ṣẹ sí ẹ lára (ip-1 352-355 ¶21-22)

Máa lo àwọn nǹkan tá a fi ń ṣèwádìí, kí ìgbàgbọ́ ẹ lè túbọ̀ lágbára

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Ais 35:8—Kí ni “Ọ̀nà Ìjẹ́mímọ́” dúró fún lónìí? (w23.05 15 ¶8)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(3 min.) ÌWÀÁSÙ NÍBI TÍ ÈRÒ PỌ̀ SÍ. Pe ẹni náà wá sípàdé. (lmd ẹ̀kọ́ 3 kókó 3)

5. Pa Dà Lọ

(4 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Fi fídíò kan láti inú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ han ẹni náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò ẹ̀. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 5)

6. Àsọyé

(5 min.) lmd àfikún A kókó 15—Àkòrí: Bíbélì Kọ́ Wa Bá A Ṣe Lè Gbàdúrà. (th ẹ̀kọ́ 14)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 41

7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 23 àti Àdúrà