February 2-8
ÀÌSÁYÀ 30-32
Orin 8 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
1. Gbà Pé Jèhófà Máa Dáàbò Bò Ẹ́
(10 min.)
Bí ẹyẹ ṣe ń dáàbò bo àwọn ọmọ ẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tó fẹ́ pa wọ́n jẹ, bẹ́ẹ̀ náà ni Jèhófà máa ń dáàbò bo àwa èèyàn rẹ̀ (Ais 31:5; w01 11/15 17 ¶7)
Má ṣe yẹra fáwọn tí Jèhófà ń lò láti ràn ẹ́ lọ́wọ́ (Ais 32:1, 2; w24.01 24 ¶13)
Máa ronú nípa ìlérí tí Jèhófà ti ṣe fún ẹ, ìyẹn á jẹ́ kó o túbọ̀ lókun (Ais 32:16-18; w23.10 17 ¶19)
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
Ais 30:20—Kí ló túmọ̀ sí nígbà tí Àìsáyà sọ pé Jèhófà máa fi “wàhálà ṣe oúnjẹ fún yín, tó sì máa fi ìyà ṣe omi fún yín”? (ip-1 310 ¶17)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Ais 31:1-9 (th ẹ̀kọ́ 10)
4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa
(4 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Ẹni náà sọ bí ohun kan tó ṣẹlẹ̀ lẹ́nu àìpẹ́ yìí ṣe ń kó o lọ́kàn sókè. (lmd ẹ̀kọ́ 2 kókó 5)
5. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa
(4 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. (lmd ẹ̀kọ́ 5 kókó 5)
6. Pa Dà Lọ
(4 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ ẹni náà. (lmd ẹ̀kọ́ 7 kókó 3)
Orin 157
7. “Àlàáfíà Ni Òdodo Tòótọ́ Máa Mú Wá”—Àyọlò
(15 min.) Ìjíròrò.
Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà. Lẹ́yìn náà, béèrè pé:
Kí lo rí kọ́ nínú fídíò yìí tó bá di pé ká fara mọ́ ìlànà òdodo Jèhófà?—Ais 32:17.
8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) lfb ẹ̀kọ́ 58-59

