Yorùbá
Ohun Tá A Máa Kọ́ ní Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ní Ọ̀sẹ̀ January 2-8, 2023
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202023001/univ/art/202023001_univ_sqr_xl.jpg
mwb23 January ojú ìwé 2

January 2-8

2 ÀWỌN ỌBA 22-23

January 2-8
  • Orin 28 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 120

  • Ṣé Onírẹ̀lẹ̀ Ni Ẹ́ àbí Agbéraga? (Jem 4:6): (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, kó o sì bi wọ́n láwọn ìbéèrè yìí: Kí ni ìyàtọ̀ tó wà nínú kéèyàn jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ àti kéèyàn jẹ́ agbéraga? Kí ni àpẹẹrẹ Mósè kọ́ wa? Kí nìdí tó o fi pinnu láti jẹ́ onírẹ̀lẹ̀?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 33

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 23 àti Àdúrà