ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ìwàásù ní January-February 2023

Yorùbá
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ìwàásù ní January-February 2023
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202023025/univ/art/202023025_univ_sqr_xl.jpg
mwb23 January ojú ìwé 16

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Nígbà Àkọ́kọ́

Ìbéèrè: Ṣé Ọlọ́run tiẹ̀ máa ń gbọ́ àdúrà?

Bíbélì: Sm 65:2

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àwọn nǹkan wo la lè bá Ọlọ́run sọ nínú àdúrà?

Ìpadàbẹ̀wò

Ìbéèrè: Àwọn nǹkan wo la lè bá Ọlọ́run sọ nínú àdúrà?

Bíbélì: 1Jo 5:14

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Ọlọ́run ṣe ń dáhùn àdúrà wa?