ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Máa Sọ Gbogbo Ohun Tó Wà Lọ́kàn Ẹ fún Jèhófà

Yorùbá
Máa Sọ Gbogbo Ohun Tó Wà Lọ́kàn Ẹ fún Jèhófà
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202022015/univ/art/202022015_univ_sqr_xl.jpg
mwb22 January ojú ìwé 10

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Máa Sọ Gbogbo Ohun Tó Wà Lọ́kàn Ẹ fún Jèhófà

Máa Sọ Gbogbo Ohun Tó Wà Lọ́kàn Ẹ fún Jèhófà

[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sámúẹ́lì Kìíní.]

Hánà gbàdúrà sí Jèhófà fún àkókò gígùn (1Sa 1:10, 12, 15; ia 55 ¶12)

Hánà fi ìṣòro ẹ̀ sílẹ̀ sọ́wọ́ Jèhófà (1Sa 1:18; w07 3/15 16 ¶3)

Tá a bá sọ gbogbo ohun tó wà lọ́kàn wa fún Jèhófà, ó dájú pé ó máa fún wa lókun, á sì ràn wá lọ́wọ́.​—Sm 55:22; 62:8.